ọwọ osi
Yoruba
    
    
Pronunciation
    
IPA(key): /ɔ̄.wɔ́ ò.sì/
Noun
    
ọwọ́ òsì
- left-hand; left side
- Synonyms: apá òsì, (euphemistic) ọwọ́ àlàáfíà
- Antonyms: ọwọ́ ọ̀tún, apá ọ̀tún
- Ọwọ́ òsì ni ó ń bẹ̀ ― It's to the left hand side
- Ẹ má lo ọwọ́ òsì láti fúnni ní nǹkan. ― Don't use the left hand to give people things.
 
Derived terms
    
- lọ́wọ́ òsì
    This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.